Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni Eliaṣibu olori alufa dide pẹlu awọn alufa arakunrin rẹ̀, nwọn si mọ ẹnu-bode agutan; nwọn sọ ọ di mimọ́, nwọn si gbe ilẹkùn rẹ̀ duro, titi de ile-iṣọ Mea, ni nwọn sọ di mimọ́ titi de ile-iṣọ Hananeeli.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:1 ni o tọ