Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu mo wi fun ọba pe, bi o ba wù ọba, ki o fun mi ni iwe si awọn bãlẹ li oke odò, ki nwọn le mu mi kọja titi emi o fi de Juda;

Ka pipe ipin Neh 2

Wo Neh 2:7 ni o tọ