Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati Sanballati ara Horoni, ati Tobiah iranṣẹ, ara Ammoni, ati Gesẹmu, ara Arabia, gbọ́, nwọn fi wa rẹrin ẹlẹya, nwọn si gàn wa, nwọn si wipe, Kini ẹnyin nṣe yi? ẹnyin o ha ṣọ̀tẹ si ọba bi?

Ka pipe ipin Neh 2

Wo Neh 2:19 ni o tọ