Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si jade li oru ni ibode afonifoji, ani niwaju kanga Dragoni, ati li ẹnu-ọ̀na ãtàn; mo si wò odi Jerusalemu ti a wó lulẹ̀, ati ẹnu-ọ̀na ti a fi iná sun.

Ka pipe ipin Neh 2

Wo Neh 2:13 ni o tọ