Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 12:9-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Bakbukiah pẹlu ati Unni, awọn arakunrin wọn, li o kọju si wọn ninu iṣọ.

10. Jeṣua si bi Joiakimu, Joiakimu si bi Eliaṣibu, Eliaṣibu si bi Joiada,

11. Joiada si bi Jonatani, Jonatani si bi Jaddua.

12. Ninu awọn alufa li ọjọ Joiakimu li awọn olori awọn baba wà: ti Seraiah, Meraiah; ti Jeremiah, Hananiah;

13. Ti Esra, Meṣullamu; ti Amariah, Jehohanani;

14. Ti Meliku, Jonatani; ti Ṣebaniah, Josefu;

15. Ti Harimu, Adna; ti Meraioti, Helkai;

16. Ti Iddo, Sekariah; ti Ginnetoni, Meṣullamu;

17. Ti Abijah, Sikri; ti Miniamini, ti Moadiah, Piltai:

18. Ti Bilga, Sammua; ti Ṣemaiah, Jehonatani;

19. Ati ti Joaribu, Mattenai; ti Jedaiah, Ussi;

20. Ti Sallai, Killai; ti Amoku, Eberi;

21. Ti Hilkiah, Haṣhabiah; ti Jedaiah, Netaneeli;

Ka pipe ipin Neh 12