Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 12:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si rekọja oke ẹnu-bode Efraimu wá, ati lati oke ẹnu-bode lailai ati li oke ẹnu-bode ẹja, ati ile-iṣọ Hananieli, ati ile-iṣọ Mea, titi de ẹnu-bode agutan, nwọn si duro li ẹnu-bode tubu.

Ka pipe ipin Neh 12

Wo Neh 12:39 ni o tọ