Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 12:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigba yiya odi Jerusalemu si mimọ́, nwọn wá awọn ọmọ Lefi kiri ninu gbogbo ibugbe wọn, lati mu wọn wá si Jerusalemu lati fi ayọ̀ ṣe iyà si mimọ́ na pẹlu idupẹ ati orin, pẹlu simbali, psalteri, ati pẹlu dùru.

Ka pipe ipin Neh 12

Wo Neh 12:27 ni o tọ