Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 12:1-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. WỌNYI si ni awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi ti o ba Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli goke lọ, ati Jeṣua: Seraiah Jeremiah, Esra,

2. Amariah, Malluki, Hattuṣi,

3. Ṣekaniah, Rehumu, Meremoti,

4. Iddo, Ginneto, Abijah,

5. Miamini, Maadiah, Bilga,

6. Ṣemaiah, ati Joiaribu, Jodaiah,

7. Sallu, Amoku, Hilkiah, Jedaiah. Wọnyi li olori awọn alufa, ati ti awọn arakunrin wọn li ọjọ Jeṣua.

8. Ati awọn ọmọ Lefi: Jeṣua, Binnui, Kadmieli, Ṣerebiah, Juda, ati Mattaniah, ti o wà lori orin idupẹ, on ati awọn arakunrin rẹ̀.

9. Bakbukiah pẹlu ati Unni, awọn arakunrin wọn, li o kọju si wọn ninu iṣọ.

10. Jeṣua si bi Joiakimu, Joiakimu si bi Eliaṣibu, Eliaṣibu si bi Joiada,

11. Joiada si bi Jonatani, Jonatani si bi Jaddua.

12. Ninu awọn alufa li ọjọ Joiakimu li awọn olori awọn baba wà: ti Seraiah, Meraiah; ti Jeremiah, Hananiah;

Ka pipe ipin Neh 12