Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nah 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, emi dojukọ́ ọ, ni Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; emi o si ká aṣọ itẹlẹ̀di rẹ li oju rẹ, emi o si fi ihòho rẹ hàn awọn orilẹ-ède, ati itiju rẹ hàn awọn ilẹ̀ ọba.

Ka pipe ipin Nah 3

Wo Nah 3:5 ni o tọ