Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mal 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enia yio ha jà Ọlọrun li olè? ṣugbọn ẹnyin sa ti jà mi li olè. Ṣugbọn ẹnyin wipe, nipa bawo li awa fi jà ọ li olè? Nipa idamẹwa ati ọrẹ.

Ka pipe ipin Mal 3

Wo Mal 3:8 ni o tọ