Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mal 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Edomu wipe, A run wa tan, ṣugbọn awa o padà, a si kọ ibùgbe ahoro wọnni; bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; Nwọn o kọ, ṣugbọn emi o wo lulẹ; Nwọn o si pe wọn ni, Agbègbe ìwa buburu, ati awọn enia ti Oluwa ni ikọnnu si titi lai.

Ka pipe ipin Mal 1

Wo Mal 1:4 ni o tọ