Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 9:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aaroni si gbé ọwọ́ rẹ̀ soke si awọn enia, o si sure fun wọn; o si sọkalẹ kuro ni ibi irubọ ẹbọ ẹ̀ṣẹ, ẹbọ sisun, ati ẹbọ alafia.

Ka pipe ipin Lef 9

Wo Lef 9:22 ni o tọ