Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú awọn ọmọ Aaroni wá, Mose si tọ́ ninu ẹ̀jẹ na si eti ọtún wọn, ati si àtampako ọwọ́ ọtún wọn, ati si àtampako ẹsẹ̀ ọtún wọn: Mose si fi ẹ̀jẹ na wọ́n ori pẹpẹ yiká.

Ka pipe ipin Lef 8

Wo Lef 8:24 ni o tọ