Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 8:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣìn ifun rẹ̀ ati itan rẹ̀ ninu omi; Mose si sun gbogbo àgbo na lori pẹpẹ: ẹbọ sisun fun õrùn didùn ni: ani ẹbọ ti a fi iná ṣe si OLUWA; bi OLUWA ti fi aṣẹ fun Mose.

Ka pipe ipin Lef 8

Wo Lef 8:21 ni o tọ