Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 8:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú ninu rẹ̀ fi wọ́n ori pẹpẹ nigba meje, o si ta a sara pẹpẹ na, ati si gbogbo ohunèlo rẹ̀, ati agbada ati ẹsẹ̀ rẹ̀, lati yà wọn simimọ́.

Ka pipe ipin Lef 8

Wo Lef 8:11 ni o tọ