Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 6:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paṣẹ fun Aaroni ati fun awọn ọmọ rẹ̀ pe, Eyi li ofin ẹbọ sisun: Ẹbọ sisun ni, nitori sisun rẹ̀ lori pẹpẹ ni gbogbo oru titi di owurọ̀, iná pẹpẹ na yio si ma jò ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 6

Wo Lef 6:9 ni o tọ