Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 6:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si sí ẹbọ ẹ̀ṣẹ kan, ẹ̀jẹ eyiti a múwa sinu agọ́ ajọ, lati fi ṣètutu ni ibi mimọ́, ti a gbọdọ jẹ: sisun ni ki a sun u ninu iná.

Ka pipe ipin Lef 6

Wo Lef 6:30 ni o tọ