Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 5:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si mú ẹbọ ẹbi rẹ̀ wá fun OLUWA, nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀ ti o ti ṣẹ̀, abo lati inu agbo-ẹran wá, ọdọ-agutan tabi ọmọ ewurẹ kan, fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ; ki alufa ki o si ṣètutu fun u nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 5

Wo Lef 5:6 ni o tọ