Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 5:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki o mú u tọ̀ alufa wá, ki alufa ki o si bù ikunwọ rẹ̀ kan ninu rẹ̀, ani ẹbọ-iranti rẹ̀, ki o si sun u lori pẹpẹ na, gẹgẹ bi ẹbọ ti a fi iná ṣe si OLUWA: ẹbọ ẹ̀ṣẹ ni.

Ka pipe ipin Lef 5

Wo Lef 5:12 ni o tọ