Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si fi diẹ ninu ẹ̀jẹ na sara iwo pẹpẹ turari didùn niwaju OLUWA, eyiti mbẹ ninu agọ́ ajọ; ki o si dà gbogbo ẹ̀jẹ akọmalu nì si isalẹ pẹpẹ ẹbọsisun, ti mbẹ li ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ.

Ka pipe ipin Lef 4

Wo Lef 4:7 ni o tọ