Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 4:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si mú gbogbo ọrá rẹ̀ kuro, bi a ti imú ọrá kuro ninu ẹbọ ọrẹ-ẹbọ alafia; ki alufa ki o si sun u lori pẹpẹ fun õrùn didùn si OLUWA; ki alufa na ki o si ṣètutu fun u, a o si dari rẹ̀ jì i.

Ka pipe ipin Lef 4

Wo Lef 4:31 ni o tọ