Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 4:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa na ki o si fi iká rẹ̀ mú ninu ẹ̀jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ na, ki o si fi i sara iwo pẹpẹ ẹbọsisun, ki o si dà ẹ̀jẹ si isalẹ pẹpẹ ẹbọsisun.

Ka pipe ipin Lef 4

Wo Lef 4:25 ni o tọ