Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi gbogbo ijọ enia Israeli ba si fi aimọ̀ ṣẹ̀, ti ohun na si pamọ́ li oju ijọ, ti nwọn si ṣì ohun kan ṣe si ọkan ninu ofin OLUWA, ti a ki ba ṣe, ti nwọn si jẹbi;

Ka pipe ipin Lef 4

Wo Lef 4:13 ni o tọ