Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 27:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn kò sí ohun ìyasọtọ kan, ti enia ba yàsọtọ fun OLUWA ninu ohun gbogbo ti o ní, ati enia, ati ẹran, ati ilẹ-iní rẹ̀, ti a gbọdọ tà tabi ti a gbọdọ rà pada: ohun gbogbo ti a ba yàsọtọ mimọ́ julọ ni si OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 27

Wo Lef 27:28 ni o tọ