Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 27:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi enia kan ba si nfẹ́ yà ninu oko ti o jogún sọ̀tọ fun OLUWA, njẹ ki idiyelé rẹ ki o jẹ́ bi irugbìn rẹ̀: òṣuwọn homeri irugbìn barle kan ãdọta ṣekeli fadakà.

Ka pipe ipin Lef 27

Wo Lef 27:16 ni o tọ