Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 27:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi enia kan yio ba si yà ile rẹ̀ sọtọ̀ lati jẹ́ mimọ́ fun OLUWA, njẹ ki alufa ki o diyelé e, ibaṣe rere tabi buburu: bi alufa ba ti diyelé e, bẹ̃ni ki o ri.

Ka pipe ipin Lef 27

Wo Lef 27:14 ni o tọ