Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi alafia si ilẹ na, ẹnyin o si dubulẹ, kò si sí ẹniti yio dẹruba nyin: emi o si mu ki ẹranko buburu ki o dasẹ kuro ni ilẹ na, bẹ̃ni idà ki yio là ilẹ nyin já.

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:6 ni o tọ