Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu gbogbo eyi, bi ẹnyin kò ba si gbọ́ ti emi, nigbana li emi o jẹ nyin ni ìya ni ìgba meje si i nitori ẹ̀ṣẹ nyin.

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:18 ni o tọ