Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ẸNYIN kò gbọdọ yá oriṣa, bẹ̃ni ẹnyin kò gbọdọ gbé ere tabi ọwọ̀n kan dide naró fun ara nyin, bẹ̃li ẹnyin kò gbọdọ gbé ere okuta gbigbẹ kalẹ ni ilẹ nyin, lati tẹriba fun u: nitoripe Emi li OLUWA Ọlọrun nyin.

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:1 ni o tọ