Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 25:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si ma fi wọn jẹ ogún fun awọn ọmọ nyin lẹhin nyin, lati ní wọn ni iní; ẹnyin o si ma sìn wọn lailai: ṣugbọn ninu awọn arakunrin nyin awọn ọmọ Israeli, ẹnikan kò gbọdọ fi irorò sìn ẹnikeji rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:46 ni o tọ