Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 25:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi o ba ṣepe on kò le san a pada fun u, njẹ ki ohun ti o tà na ki o gbé ọwọ́ ẹniti o rà a titi di ọdún jubeli: yio si bọ́ ni jubeli, on o si pada lọ si ilẹ-iní rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:28 ni o tọ