Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 25:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sọ fun awọn ọmọ Israeli, ki o si wi fun wọn pe, Nigbati ẹnyin ba dé ilẹ ti mo fi fun nyin, nigbana ni ki ilẹ na ki o pa isimi kan mọ́ fun OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:2 ni o tọ