Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 25:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o si yà arãdọta ọdún simimọ́, ki ẹnyin ki o si kede idasilẹ ni ilẹ na fun gbogbo awọn ti ngbé inu rẹ̀: yio si ma jẹ́ jubeli fun nyin; ki ẹnyin ki o si pada olukuluku si ilẹ-iní rẹ̀, ki olukuluku nyin ki o si pada sinu idile rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:10 ni o tọ