Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 24:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ẹniti o sọ̀rọ buburu si orukọ OLUWA nì, pipa ni ki a pa a: gbogbo ijọ enia ni ki o sọ ọ li okuta pa nitõtọ: ati alejò, ati ibilẹ, nigbati o ba sọ̀rọbuburu si orukọ OLUWA, pipa li a o pa a.

Ka pipe ipin Lef 24

Wo Lef 24:16 ni o tọ