Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 22:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ki nwọn ki o ma pa ìlana mi mọ́, ki nwọn ki o máṣe rù ẹ̀ṣẹ nitori rẹ̀, nwọn a si kú nitorina, bi nwọn ba bà a jẹ́: Emi li OLUWA ti o yà wọn simimọ́.

Ka pipe ipin Lef 22

Wo Lef 22:9 ni o tọ