Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 22:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikẹni ninu irú-ọmọ Aaroni ti iṣe adẹtẹ, tabi ti o ní isun; ki o máṣe jẹ ninu ohun mimọ́, titi on o fi di mimọ́. Ati ẹnikẹni ti o farakàn ohun ti iṣe aimọ́, bi okú, tabi ọkunrin ti ohun-irú nti ara rẹ̀ jade;

Ka pipe ipin Lef 22

Wo Lef 22:4 ni o tọ