Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 22:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a ba bi akọmalu kan, tabi agutan kan, tabi ewurẹ kan, nigbana ni ki o gbé ijọ meje lọdọ iya rẹ̀; ati lati ijọ́ kẹjọ ati titi lọ on o di itẹwọgbà fun ẹbọ ti a fi iná ṣe si OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 22

Wo Lef 22:27 ni o tọ