Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 22:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni ẹnyin kò gbọdọ ti ọwọ́ alejò rubọ àkara Ọlọrun nyin ninu gbogbo wọnyi; nitoripe ibàjẹ́ wọn mbẹ ninu wọn, abùku si mbẹ ninu wọn: nwọn ki yio dà fun nyin.

Ka pipe ipin Lef 22

Wo Lef 22:25 ni o tọ