Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 22:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ọmọbinrin alufa na ba di opó, tabi ẹni-ikọsilẹ, ti kò si lí ọmọ, ti o si pada wá si ile baba rẹ̀, bi ìgba ewe rẹ̀, ki o ma jẹ ninu onjẹ baba rẹ̀: ṣugbọn alejò kan kò gbọdọ jẹ ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 22

Wo Lef 22:13 ni o tọ