Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 21:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati olori alufa ninu awọn arakunrin rẹ̀, ori ẹniti a dà oróro itasori si, ti a si yàsọtọ lati ma wọ̀ aṣọ wọnni, ki o máṣe ṣi ibori rẹ̀, tabi ki o fà aṣọ rẹ̀ ya;

Ka pipe ipin Lef 21

Wo Lef 21:10 ni o tọ