Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Alufa yio si mú ẹbọ-iranti ninu ohunjijẹ na, yio si sun u lori pẹpẹ: ẹbọ ti a fi iná ṣe, õrùn didùn si OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 2

Wo Lef 2:9 ni o tọ