Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 19:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oṣuwọn otitọ, òṣuwọn iwuwo otitọ, òṣuwọn efa otitọ, ati òṣuwọn hini otitọ, ni ki ẹnyin ki o ní: Emi li OLUWA Ọlọrun nyin, ti o mú nyin lati ilẹ Egipti jade wá.

Ka pipe ipin Lef 19

Wo Lef 19:36 ni o tọ