Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 19:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alejò ti mbá nyin gbé ki o jasi fun nyin bi ibilẹ, ki iwọ ki o si fẹ́ ẹ bi ara rẹ; nitoripe ẹnyin ti ṣe alejò ni ilẹ Egipti: Emi li OLUWA Ọlọrun nyin.

Ka pipe ipin Lef 19

Wo Lef 19:34 ni o tọ