Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 19:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ẹnikẹni ti o ba bá obinrin dàpọ, ti iṣe ẹrú, ti a fẹ́ fun ọkọ, ti a kò ti ràpada rára, ti a kò ti sọ di omnira; ọ̀ran ìna ni; ki a máṣe pa wọn, nitoriti obinrin na ki iṣe omnira.

Ka pipe ipin Lef 19

Wo Lef 19:20 ni o tọ