Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 16:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati alufa na, ẹniti a o ta oróro si li ori, ati ẹniti a o yàsimimọ́ si iṣẹ-alufa dipò baba rẹ̀, on ni ki o ṣètutu na, ki o si mú aṣọ ọ̀gbọ wọnni wọ̀, ani aṣọ mimọ́ wọnni:

Ka pipe ipin Lef 16

Wo Lef 16:32 ni o tọ