Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 16:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki o pa ewurẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ, eyiti iṣe ti awọn enia, ki o si mú ẹ̀jẹ rẹ̀ wá sinu aṣọ-ikele, ki o si fi ẹ̀jẹ na ṣe bi o ti fi ẹ̀jẹ akọmalu ṣe, ki o si fi wọ́n ori itẹ̀-ãnu, ati niwaju itẹ́-ãnu:

Ka pipe ipin Lef 16

Wo Lef 16:15 ni o tọ