Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si wó ile na, okuta rẹ̀, ati ìti igi rẹ̀, ati gbogbo erupẹ ile na; ki o si kó wọn jade kuro ninu ilu na lọ si ibi aimọ́ kan.

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:45 ni o tọ