Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki alufa ki o fun wọn li aṣẹ, ki nwọn ki o kó ohun ile na jade, ki alufa ki o to wọ̀ inu rẹ̀ lọ lati wò àrun na, ki ohun gbogbo ti mbẹ ninu ile na ki o máṣe jẹ́ alaimọ́: lẹhin eyinì ni ki alufa ki o wọ̀ ọ lati wò ile na:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:36 ni o tọ