Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si fi ninu oróro na ti mbẹ li ọwọ́ rẹ̀ si eti ọtún ẹniti a o wẹ̀numọ́, ati si àtampako ọwọ́ ọtún rẹ̀, ati si àtampako ẹsẹ̀ ọtún rẹ̀, si ibi ẹ̀jẹ ẹbọ ẹbi:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:28 ni o tọ