Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si pa ọdọ-agutan ẹbọ ẹbi, ki alufa ki o si mú ninu ẹ̀jẹ ẹbọ ẹbi na, ki o si fi i si etí ọtún ẹniti a o wẹ̀numọ́, ati si àtampako ọwọ́ ọtún rẹ̀, ati si àtampako ẹsẹ̀ ọtún rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:25 ni o tọ